Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, mo sọ fún wọn pé, “Ṣé ẹ rí irú ìyọnu tí ó dé bá wa! Ẹ wò ó bí Jerusalẹmu ṣe parun tí àwọn ẹnu ọ̀nà rẹ̀ sì jóná. Ẹ múra, ẹ jẹ́ kí á kọ́ odi Jerusalẹmu, kí á lè fi òpin sí ìtìjú tí ó dé bá wa.”

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:17 ni o tọ