Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè náà kò sì mọ ibi tí mo lọ tabi ohun tí mo lọ ṣe, n kò sì tíì sọ nǹkankan fún àwọn Juu, ẹlẹgbẹ́ mi: àwọn alufaa, ati àwọn ọlọ́lá, tabi àwọn ìjòyè ati àwọn yòókù tí wọn yóo jọ ṣe iṣẹ́ náà.

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:16 ni o tọ