Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbéra lóru, mo gba Ẹnubodè Àfonífojì. Mo jáde sí kànga Diragoni, mo gba ibẹ̀ lọ sí Ẹnubodè Ààtàn. Bí mo ti ń lọ, mò ń wo àwọn ògiri Jerusalẹmu tí wọ́n ti wó lulẹ̀ ati àwọn ẹnu ọ̀nà tí wọ́n ti jó níná.

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:13 ni o tọ