Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbéra ní alẹ́ èmi ati àwọn eniyan díẹ̀, ṣugbọn n kò sọ ohun tí Ọlọrun mi fi sí mi lọ́kàn láti ṣe ní Jerusalẹmu fún ẹnikẹ́ni. Kò sí ẹranko kankan pẹlu mi àfi kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tí mo gùn.

Ka pipe ipin Nehemaya 2

Wo Nehemaya 2:12 ni o tọ