Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 11:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè ní àwọn agbègbè wọn ń gbé Jerusalẹmu, ṣugbọn ní àwọn ìlú Juda, olukuluku àwọn ọmọ Israẹli ń gbé orí ilẹ̀ rẹ̀, ní ìlú wọn, títí kan àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi, àwọn iranṣẹ tẹmpili, ati àwọn ìran iranṣẹ Solomoni.

Ka pipe ipin Nehemaya 11

Wo Nehemaya 11:3 ni o tọ