Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:35 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti gbà á bí ojúṣe wa pé àkọ́so èso ilẹ̀ wa ati àkọ́so gbogbo èso igi wa lọdọọdun, ni a óo máa gbé wá sí ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Nehemaya 10

Wo Nehemaya 10:35 ni o tọ