Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:34 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti dìbò láàrin àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi ati àwọn eniyan, bí wọn yóo ṣe máa ru igi wá sí ilé Ọlọrun wa, ní oníléjilé, ní ìdílé ìdílé, ní àwọn àkókò tí a yàn lọdọọdun, tí wọn yóo fi máa rúbọ lórí pẹpẹ OLUWA Ọlọrun wa, gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ sinu ìwé òfin.

Ka pipe ipin Nehemaya 10

Wo Nehemaya 10:34 ni o tọ