Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:20-29 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Magipiaṣi, Meṣulamu, ati Hesiri,

21. Meṣesabeli, Sadoku, ati Jadua,

22. Pelataya, Hanani, ati Anaaya,

23. Hoṣea, Hananaya, ati Haṣubu,

24. Haloheṣi, Pileha, ati Ṣobeki,

25. Rehumu, Haṣabina, ati Maaseaya,

26. Ahija, Hanani, ati Anani,

27. Maluki, Harimu, ati Baana.

28. Àwọn eniyan yòókù, àwọn alufaa, àwọn ọmọ Lefi, àwọn aṣọ́nà, àwọn akọrin, àwọn iranṣẹ tẹmpili ati àwọn tí wọ́n ti ya ara wọn sọ́tọ̀ kúrò lọ́dọ̀ àwọn eniyan ilẹ̀ náà gẹ́gẹ́ bí òfin Ọlọrun, àwọn iyawo wọn, àwọn ọmọ wọn ọkunrin, àwọn ọmọ wọn obinrin, gbogbo àwọn tí wọ́n gbọ́njú mọ ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀,

29. wọ́n parapọ̀ pẹlu àwọn arakunrin wọn ati àwọn ọlọ́lá wọn; wọ́n gégùn-ún, wọ́n sì búra pé àwọn ó máa pa òfin Ọlọrun mọ́, àwọn óo sì máa tẹ̀lé e, bí Mose iranṣẹ rẹ̀ ti fún wọn. Wọ́n óo máa ṣe gbogbo ohun tí OLUWA tíí ṣe Oluwa wọn paláṣẹ, wọn ó sì máa tẹ̀lé ìlànà ati òfin rẹ̀.

Ka pipe ipin Nehemaya 10