Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 10:30 BIBELI MIMỌ (BM)

A kò ní fi àwọn ọmọ wa obinrin fún àwọn ọmọ àwọn àlejò tí ń gbé ilẹ̀ wa, bẹ́ẹ̀ ni a kò ní fẹ́ àwọn ọmọbinrin wọn fún àwọn ọmọ wa.

Ka pipe ipin Nehemaya 10

Wo Nehemaya 10:30 ni o tọ