Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 1:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún mi pé, “Inú wahala ńlá ati ìtìjú ni àwọn tí wọ́n ṣẹ́kù, tí wọn kò kó lẹ́rú wà, ati pé odi Jerusalẹmu ti wó lulẹ̀, iná sì ti jó gbogbo ẹnu ọ̀nà rẹ̀.”

Ka pipe ipin Nehemaya 1

Wo Nehemaya 1:3 ni o tọ