Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nehemaya 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Hanani, ọ̀kan ninu àwọn arakunrin mi, pẹlu àwọn kan tọ̀ mí wá láti ilẹ̀ Juda, mo bá bèèrè àwọn Juu tí wọ́n ṣẹ́kù, tí wọn kò kó lọ sóko ẹrú, mo sì tún bèèrè nípa Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Nehemaya 1

Wo Nehemaya 1:2 ni o tọ