Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nahumu 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbo ni ìlú tí ó dàbí ihò àwọn kinniun wà?Tí ó rí bí ibùgbé àwọn ọ̀dọ́ kinniun?Ibi tí kinniun ń gbé oúnjẹ rẹ̀ lọ,tí àwọn ọmọ rẹ̀ wà,tí kò sí ẹni tí ó lè dà wọ́n láàmú?

Ka pipe ipin Nahumu 2

Wo Nahumu 2:11 ni o tọ