Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nahumu 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ti pàṣẹ nípa Asiria, pé: “A kò ní ranti orúkọ rẹ mọ́, ìwọ ilẹ̀ Asiria, n óo run àwọn ère tí ẹ̀yin ará Asiria gbẹ́, ati àwọn tí ẹ dà, tí wọ́n wà ní ilé oriṣa rẹ, n óo gbẹ́ ibojì rẹ, nítorí ẹlẹ́gbin ni ọ́.”

Ka pipe ipin Nahumu 1

Wo Nahumu 1:14 ni o tọ