Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nahumu 1:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí pé: “Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn ará Siria lágbára, tí wọ́n sì pọ̀, a óo pa wọ́n run, wọn yóo sì parẹ́. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mo ti jẹ ẹ̀yin ọmọ Juda níyà tẹ́lẹ̀, n kò ní jẹ yín níyà mọ́.

Ka pipe ipin Nahumu 1

Wo Nahumu 1:12 ni o tọ