Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mika 2:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Dájúdájú, n óo kó gbogbo yín jọ, ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, n óo kó àwọn ọmọ Israẹli yòókù jọ: n óo kó wọn pọ̀ bí aguntan, sinu agbo, àní bí agbo ẹran ninu pápá, ariwo yóo sì pọ̀ ninu agbo náà, nítorí ọ̀pọ̀ eniyan.”

Ka pipe ipin Mika 2

Wo Mika 2:12 ni o tọ