Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 9:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Aaroni bá súnmọ́ ibi pẹpẹ náà, ó pa ọ̀dọ́ mààlúù fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:8 ni o tọ