Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 8:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú burẹdi dídùn kan tí kò ní ìwúkàrà ninu, ninu agbọ̀n burẹdi tí ó wà níwájú OLUWA, ati burẹdi olóròóró kan tí kò ní ìwúkàrà ninu ati burẹdi fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ kan, ó kó wọn lé orí ọ̀rá náà ati itan ọ̀tún àgbò náà.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:26 ni o tọ