Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 8:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó mú ọ̀rá àgbò náà, ati ọ̀rá ìrù rẹ̀, ati gbogbo ọ̀rá tí ó bo àwọn nǹkan inú rẹ̀, ati ẹ̀dọ̀ rẹ̀, ati kíndìnrín rẹ̀ mejeeji pẹlu ọ̀rá tí ó wà lára wọn, ati itan ọ̀tún rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:25 ni o tọ