Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 8:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó fa àgbò keji kalẹ̀, èyí tí í ṣe àgbò ìyàsímímọ́. Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ gbé ọwọ́ wọn lé e lórí.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:22 ni o tọ