Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 8:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó fọ nǹkan inú rẹ̀ ati ẹsẹ̀ rẹ̀, ó fi gbogbo rẹ̀ rú ẹbọ sísun, ẹbọ olóòórùn dídùn tí a fi iná sun sí OLUWA, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:21 ni o tọ