Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 7:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Òfin ẹbọ sísun ni, ati ti ẹbọ ohun jíjẹ, ti ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, ati ti ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀bi, ti ẹbọ ìyàsímímọ́, ati ti ẹbọ alaafia;

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:37 ni o tọ