Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn bí ẹbọ ọrẹ rẹ̀ bá jẹ́ ti ẹ̀jẹ́ tabi ọrẹ àtinúwá, wọ́n gbọdọ̀ jẹ ẹ́ ní ọjọ́ náà, ṣugbọn bí ó bá ṣẹ́kù, wọ́n lè jẹ ẹ́ ní ọjọ́ keji;

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:16 ni o tọ