Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 7:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ ẹran ẹbọ alaafia tí ó fi ṣe ẹbọ ọpẹ́ tán ní ọjọ́ tí ó bá rú ẹbọ náà, kò gbọdọ̀ ṣẹ́kù di ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:15 ni o tọ