Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti ìka rẹ̀ bọ inú ẹ̀jẹ̀ náà, yóo sì wọ́n ọn sílẹ̀ nígbà meje níwájú OLUWA, níwájú aṣọ ìkélé tí ó wà ní ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:6 ni o tọ