Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

nígbà tí wọ́n bá mọ ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá, tí wọ́n sì rí àṣìṣe wọn, gbogbo ìjọ eniyan náà yóo fi ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀, wọn yóo fà á wá síbi Àgọ́ Àjọ.

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:14 ni o tọ