Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tí ó bá jẹ́ pé gbogbo ìjọ eniyan Israẹli ni ó ṣèèṣì dẹ́ṣẹ̀, ṣugbọn tí ẹ̀ṣẹ̀ náà kò hàn sí ìjọ eniyan, tí wọ́n bá ṣe ọ̀kan ninu àwọn ohun gbogbo tí OLUWA ti pa láṣẹ fún wọn pé wọn kò gbọdọ̀ ṣe, tí wọ́n sì jẹ̀bi,

Ka pipe ipin Lefitiku 4

Wo Lefitiku 4:13 ni o tọ