Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 27:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá jẹ́ ẹran tí kò mọ́, kí ó san owó rẹ̀ pada gẹ́gẹ́ bí iye tí ẹ bá dá lé e, kí ó sì fi ìdámárùn-ún owó náà lé e. Bí ẹni tí ó ni í kò bá sì rà á pada, kí wọ́n tà á ní iyekíye tí ẹ bá dá lé e.

Ka pipe ipin Lefitiku 27

Wo Lefitiku 27:27 ni o tọ