Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdún mẹfa ni kí ẹ máa fi gbin èso sinu oko yín, ọdún mẹfa náà sì ni kí ẹ máa fi tọ́jú ọgbà àjàrà yín, tí ẹ óo sì máa fi kórè èso rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:3 ni o tọ