Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 25:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí n óo fun yín, àkókò ìyàsọ́tọ̀ kan gbọdọ̀ wà fún ilẹ̀ náà tí yóo jẹ́ àkókò ìsinmi fún OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 25

Wo Lefitiku 25:2 ni o tọ