Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 24:12-14 BIBELI MIMỌ (BM)

12. Wọ́n tì í mọ́lé títí tí wọn fi mọ ohun tí OLUWA fẹ́ kí wọ́n ṣe sí i.

13. OLUWA sọ fún Mose pé,

14. “Mú ọkunrin tí ó ṣépè náà jáde kúrò láàrin ibùdó, kí gbogbo àwọn tí wọ́n gbọ́ nígbà tí ó ṣépè gbé ọwọ́ lé e lórí, kí gbogbo ìjọ eniyan sì sọ ọ́ ní òkúta pa.

Ka pipe ipin Lefitiku 24