Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 24:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wí fún àwọn eniyan Israẹli pé, ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣépè lé Ọlọrun rẹ̀ yóo ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ nítorí rẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 24

Wo Lefitiku 24:15 ni o tọ