Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:39 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn tí ẹ bá ti kórè àwọn èso ilẹ̀ yín tán, láti ọjọ́ kẹẹdogun oṣù keje lọ, kí ẹ máa ṣe àjọ àjọ̀dún OLUWA fún ọjọ́ meje; ọjọ́ kinni ati ọjọ́ kẹjọ yóo jẹ́ ọjọ́ ìsinmi tí ó lọ́wọ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:39 ni o tọ