Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹbọ wọnyi wà lọ́tọ̀ ní tiwọn, yàtọ̀ sí ti àwọn ọjọ́ ìsinmi fún OLUWA, ati àwọn ẹ̀bùn yín, ati àwọn ẹbọ ẹ̀jẹ́ yín, ati àwọn ọrẹ ẹbọ àtinúwá tí ẹ óo máa mú wá fún OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:38 ni o tọ