Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 23:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ meje ni ẹ óo fi máa rú ẹbọ sísun sí OLUWA. Ní ọjọ́ kẹjọ, ẹ óo ní ìpéjọpọ̀ mímọ́, ẹ óo sì rú ẹbọ sísun sí OLUWA. Ìpéjọpọ̀ tí ó lọ́wọ̀ ni, nítorí náà, ẹ kò gbọdọ̀ ṣe iṣẹ́ líle kankan.

Ka pipe ipin Lefitiku 23

Wo Lefitiku 23:36 ni o tọ