Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn alufaa gbọdọ̀ pa àwọn òfin mi mọ́, kí wọ́n má baà dẹ́ṣẹ̀ nítorí rẹ̀, kí wọ́n sì kú nítorí àwọn òfin mi tí wọ́n bá rú. Èmi ni OLUWA tí mo sọ wọ́n di mímọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:9 ni o tọ