Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Alufaa kò gbọdọ̀ jẹ ohunkohun tí ó bá kú fúnrara rẹ̀, tabi tí ẹranko burúkú bá pa; kí ó má baà fi òkú ẹran yìí sọ ara rẹ̀ di aláìmọ́. Èmi ni OLUWA.

Ka pipe ipin Lefitiku 22

Wo Lefitiku 22:8 ni o tọ