Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbé àwọn ẹbọ ohun jíjẹ náà wá siwaju OLUWA. Nígbà tí o bá gbé e fún alufaa, yóo gbé e wá síbi pẹpẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:8 ni o tọ