Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí o bá fẹ́ fi àkọ́so oko rẹ rú ẹbọ ohun jíjẹ sí OLUWA, ninu ṣiiri ọkà àkọ́so oko rẹ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ pa ni kí o ti mú, kí o yan án lórí iná.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:14 ni o tọ