Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹbọ ohun jíjẹ rẹ ni o gbọdọ̀ fi iyọ̀ sí, o kò gbọdọ̀ jẹ́ kí iyọ̀ wọ́n ninu ọrẹ ohun jíjẹ rẹ; nítorí pé iyọ̀ ni ẹ̀rí majẹmu láàrin ìwọ pẹlu Ọlọrun rẹ, o níláti máa fi iyọ̀ sí gbogbo ẹbọ rẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 2

Wo Lefitiku 2:13 ni o tọ