Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 19:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí o bá ń kórè oko rẹ, o kò gbọdọ̀ kórè títí kan ààlà. Lẹ́yìn tí o bá ti kórè tán, o kò gbọdọ̀ pada lọ tún kórè àwọn ohun tí o bá gbàgbé.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:9 ni o tọ