Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ kórè gbogbo àjàrà rẹ tán patapata, o kò sì gbọdọ̀ ṣa àwọn èso tí ó bá rẹ̀ sílẹ̀ ninu ọgbà àjàrà rẹ, o níláti fi wọ́n sílẹ̀ fún àwọn talaka ati àwọn àlejò. Èmi ni OLUWA Ọlọrun rẹ.

Ka pipe ipin Lefitiku 19

Wo Lefitiku 19:10 ni o tọ