Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ Israẹli, tabi àwọn àlejò tí ń ṣe àtìpó láàrin wọn tí ó bá lọ ṣe ọdẹ tí ó sì pa ẹran tabi ẹyẹ tí eniyan lè jẹ, ó níláti ro gbogbo ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sílẹ̀ kí ó sì wa erùpẹ̀ bò ó.

Ka pipe ipin Lefitiku 17

Wo Lefitiku 17:13 ni o tọ