Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 17:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí rẹ̀ ni mo fi sọ fún ẹ̀yin ọmọ Israẹli pé, ẹnikẹ́ni ninu yín kò gbọdọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀, bẹ́ẹ̀ sì ni àlejò tí ń ṣe àtìpó láàrin yín kò gbọdọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 17

Wo Lefitiku 17:12 ni o tọ