Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 16:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo sì fi ìka wọ́n díẹ̀ ninu ẹ̀jẹ̀ náà sí ara pẹpẹ nígbà meje, yóo sọ ọ́ di mímọ́, yóo sì yà á sí mímọ́ kúrò ninu àìmọ́ àwọn eniyan Israẹli.

Ka pipe ipin Lefitiku 16

Wo Lefitiku 16:19 ni o tọ