Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 15:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí obinrin bá ń ṣe nǹkan oṣù rẹ̀, kí ó wà ní ipò àìmọ́ fún ọjọ́ meje. Ẹnikẹ́ni tí ó bá sì fi ara kàn án jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:19 ni o tọ