Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 15:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ọkunrin bá bá obinrin lòpọ̀, tí nǹkan ọkunrin sì jáde lára rẹ̀, kí àwọn mejeeji wẹ̀, kí wọ́n sì jẹ́ aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 15

Wo Lefitiku 15:18 ni o tọ