Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo mú ẹyẹ tí ó wà láàyè ati igi kedari, ati aṣọ pupa tẹ́ẹ́rẹ́, ati ewé hisopu, yóo pa wọ́n pọ̀, yóo sì tì wọ́n bọ inú ẹ̀jẹ̀ ẹyẹ tí wọ́n pa lórí odò tí ń ṣàn.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:6 ni o tọ