Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 14:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo pàṣẹ pé kí wọ́n ha gbogbo ògiri ilé náà yípo, kí wọ́n kó gbogbo ohun tí wọ́n fi rẹ́ ilé, tí wọ́n ha kúrò, kí wọ́n dà á sí ibìkan tí kò mọ́ lẹ́yìn ìlú.

Ka pipe ipin Lefitiku 14

Wo Lefitiku 14:41 ni o tọ