Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:46 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo jẹ́ aláìmọ́, níwọ̀n ìgbà tí àrùn yìí bá wà lára rẹ̀. Ó jẹ́ aláìmọ́; òun nìkan ni yóo sì máa dá gbé lẹ́yìn ibùdó.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:46 ni o tọ