Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lefitiku 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí alufaa bá yẹ̀ ẹ́ wò, tí irun ọ̀gangan ibẹ̀ kò sì di funfun, tí wúwú tí ó wú kò sì jìn ju awọ ara olúwarẹ̀ lọ, ṣugbọn tí ó wòdú, kí alufaa ti ẹni náà mọ́lé fún ọjọ́ meje.

Ka pipe ipin Lefitiku 13

Wo Lefitiku 13:21 ni o tọ